Bayray McNwizu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Eberechukwu Nwizu |
Iṣẹ́ | òṣèrébìnrin |
Notable work | Calabash |
Eberechukwu Nwizu [1] tí a tún mọ̀ sí Bhaira Mcwizu tàbí Bayray McNwizu jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3] O dí gbajúmò lẹ́hìn tí ó gbégbá orókè níbi ètò Amstel Malta Box Office (AMBO) ẹlékẹẹ̀ta. Ní ọdún 2009, wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ kan ti Africa Movie Academy Awards.[4][5]
Ọdún | Àkọ́lé | Ipa | Olùdarí | Ìtọ́kasí |
---|---|---|---|---|
2015 | Lekki Wives Season 3 | N/A | Blessing Egbe | [6] |
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)