Shan George | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Cross River, Naijiria. |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Naijiria. |
Ẹ̀kọ́ | Mass Communication, University of Lagos |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | olorin, osere ati adari ere |
Notable work | Thorns Of Rose |
Shan George je olorin, osere ati adari ere ni orile ede Naijiria.[1] Ki o to kopa ninu ere Thorns of Rose, o ti kopa ninu ere Wind of Destiny ni odun 1997. O di gbajumo nipa ipa ti o ko ninu ere Outkast ati Welcome to Nollywood.[2]
Won bi Shan si ilu Abi ni ipinle Cross River ni orile ede Naijiria. Mama re je omo orile ede Naijiria sugbon baba re je oyinbo.[3] O se igbeyawo akoko re nigba ti o wa ni omo odun merin di logun. O lo si ile eko giga ti University of Lagos nibi ti o ti gboye ninu eko Mass Communication, nibe si ni o ti se ere All for Winnie.[4]
Ni odun 2010, Shan se agbekale orin ti o pe akole re ni Ijo. Orin na si gbajumo gan.[5] Laarin awon ere ti o ti se ni ni Thorns Of Rose, London Forever, Super Zebraman, A Second Time, Grand Mother, Passionate, Crime, One Good Man[6], Do Good . Shan ti bi omo meji.[7]
|url-status=
ignored (help)