Shridath Ramphal Awọ̀wé àgbà àgbáyé láti ọdún 1975 sí ọdún 1990.

Sir Shridath Surendranath "Sonny" Ramphal, GCMG, AC, ONZ, OE, OM, QC, FRSA (ojoibi 3 October 1928, New Amsterdam, British Guiana) lo je Akowe Agba Ajoni awon Orile-ede keji lati 1975 de 1990. Ramphal teletele lo je Alakoso Oro Okere ile Guyana lati 1972 de 1975.



Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.

Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.

Itokasi